20/05/2026
Alaga yin ti de ooo
Mo ma n se agbenuso fun idile oko tabi Iyawo ni ojo igbeyawo awon omo won
Mo ma n di eru Iyawo pelu afihan re ni ona to yayi to si rewa loju.
Mo ma n ta leta igbero ati itewogba ni owo ti ko gun pa
Mo le rin irinajo losi ilu tabi orileede lati darapo mo igbeyawo yin ti ina wa ba wo
Emi ni Alaga asiko yin — Irede Alaga