11/11/2025
* Keere o..................
*Onile
*Alejo
*Lokunrin
*Lobinrin
*Lomode
*Lagba
*Oba awon oba ti nse Arugbo ojo lo ranmi si yin o! oni ki nso fun yin pe: *Bi odun yi ti npari lo
*E oni sunkun lori awon omo yin
*E oni sunkun lori oko yin
*E oni sunkun lori aya yin
*E oni se odun ninu iponju ati ibanuje
*E oni kosi nu panpe aye
*Won oni bo bata ofo senu ona yin
*Ijanba koni sele si yin
*Iji aye koni ja yin
*Ire to ku lodun yi yio ya sile yin
*Arelu ibi koni sele si yin
*Ayo ati alafiaa ni a o fi se odun yi ati odun to nbo*
*Mowi ire abi mi o wi ire❓*
*Ti mo ba wi ire, fi Adura yi ranse si eniyan ti o ba feran
*Ese pupo🤷🏻♂️*