28/09/2026
Irin ajo wa lọ̀sẹ̀ yìí kì o mú ẹkún kikoro dání fún èmi àti eyín.
Ọlọ́run yóò tọ́ wa sí ona rere,
yóò sì fi ayọ̀, àlàáfíà àti ìṣẹ́gun fun wa.
A ó rí ìbùkún ní gbogbo ìgbésẹ̀ wa.🙏
́gun